Posts

Captain Nurudeen Ogunlade. Afinju omo Oodua to mu idagbasoke wa si ipinle Osun.

Meet Captain Nurudeen Ogunlade. The determined patriot who made History in the State of Osun.

Awon omoologun Nigeria mu awon Fulani darandaran mefa ni ipinle Adamawa.

Buhari, Osinbajo, Okorocha, Oyegun, El-Rufai, Amosun, Bello. Shettima, Ambode, Akeredolu, Ortom, peju sibi ipade APC National Executive Committee meeting loni.

Odomode olorin Adekunle Gold se idaro aburo re lori ero ayelujara instagram.

#BBNaija; Ogbeni Tobi ti dibo lati le arabirin Cee C kuro ninu idije Big Brother Naija. (MOMMY TOBI, E KU ISE O, Abiamo tooto).)

Aare Buhari se ipade pelu awon oluko ile iwe giga UNIMAID ti awon agbesunmomi Bokoharam sese tu sile.

Emi ni mo ko Davido ati Bred ni ise orin kiko. Senator Ademola Adeleke lo so be.