Gbajugbaja odomode olorin Davido ra oko ayokele Porshe fun Chioma ololufe re lati fi se ayeye ojo ibi re April 30, 2018
Awon aworan nibi ipade to waye laarin Aare orilede America Donald Trump ati Aare Buhari April 30, 2018
Awon omo leyin Krisiti to wa ni ipinle Benue se iwode ita gban-gba latari ipaniyan ojojumo ton sele ni ipinle na April 29, 2018
Aare Buhari ti de orilede America lati gbaradi fun ipade re pelu Aare orilede na, Donald Trump April 29, 2018
Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki lo se abewo si awon agunbaniro to wa ni ipinle Kwara April 29, 2018
Aare Buhari, Igbakeji Aare Yemi Osinbajo, Aliko Dangote, Otunba Niyi Adebayo peju sibi ayeye igbeyawo omo oga SGF, Mustapha Boss April 28, 2018