Posts

Owo awon omo ologun Nigeria ti ba meji ninu awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam.

Aworan nibi ayeye igbeyawo gbajugbaja odomode agbaboolu Lionel Messi ati ololufe re Antonella Roccuzzo

Tonto Dikeh, Mercy Aigbe, Dolapo Badmus, Foluke Daramola, fowo sowopo pelu Olori Wuraola lati se iwode fun ilodi si ifiya je ati ilokulo awon obirin ni awujo wa.

Kini Rochas Okorocha tun gba lowo Femi Fani Kayode bayi?

Ololufe mi dakun mabinu. Lanre Gentry lo so be.

Owo ba ole kan nibi to ti fe ji ege (cassava) wa ni ilu Akwa Ibom.

Iya Utibe, omo ti Davido se lanu ti ku.

Epo n be, Ewa n be. Gbajugbaja odomode agbaboolu Cristiano Ronaldo ti bi ibeji.

Hush puppi, Phyno, Iceprince ati Kcee fi oro buruku ranse si ara won lori ero ayelujara Snapchat.

Hmmmmmmmmmm o ga o !

Meji ninu awon omobirin chibok to salo mo awon agbesunmomi Bokoharam lowo, lo se ipade pelu Aare orilede America Donald Trump.

Aye le o Ibosi o. Alaboyun kan bi alangba ni Ipinle Rivers.

Awon Fulani Daran-daran pa arakunrin kan ninu oko re ni ipinle Delta. +18