Posts

Alo o, Alo!, Orilede wo lo wa ti Aare won o ti de ibe fun Osu meji? Ile ise iroyin CNN lo pa alo apamo.

Awon adigunjale pa awon osise Customs meji ni ilu Katsina.

Omo Emir Kano nigbakan Sadiku Bayero ti se tan lati se igbeyawo.

Awon omo egbe okunkun Badoo to n' pa eyan ni ipinle Eko tun ti pa awon marun ninu idile kan. +18

Awon agbenipa pa Oba kan ni ipinle Ondo.

Ijoba ipinle Eko ti bere si wo awon ile ti won ko si oju opopona ni Obalende.

Omobirin Gomina ipinle Jigawa nigba kan ri ti ku.

Aare orilede Ghana nigbakan ri John Mahama ati iyawo re Lordina se ayeye ayajo odun karundinlogbon (25years) igbeyawo won.

Emi ati oko mi sunmo ara wa peki-peki, koda ama n'wo pata ara wa. Iyawo ologbe Adebayo Faleti lo so be.

Okere tan awon eyan mewa lo ti jona ninu ijamba oko to waye ni opopona Abuja si Lokoja. +18

15 million ni mo fe fi se ayeye ojo ibi mi ton bo lona. Arakunrin ati Arabirin Bobriski lo so be.