Posts

Aare Buhari ti fowosi abadofin to fun awon odo ni oreofe lati gbegba oselu #NotTooYoungToRun

O ma se o! Oga agba ile ise iwe iroyin Punch;Wale Aboderin ti ku

Zinedine Zidane ti ko iwe fi ise sile gege bi oluko agba egbe agbaboolu Real Madrid

Awon aworan nibi ayeye igbeyawo Mocheddah ati Bukunyi Olateru

Ajo Efcc ti gbe Gomina ipinle Kaduna nigbakanri Ramalan Yero ju si atimole fun esun jibiti

Ile ejo ti fi Gomina ipinle Taraba nigbakanri Jolly Nyame si ewon odun merila fun esun jibiti

Awon omo egbe agbaboolu Super Eagles se ipade pelu Aare Buhari ni Abuja loni

Senator Dino Melaye ti kuro ninu egbe oloselu APC bo si egbe oloselu PDP

Oserekunrin Michael Okon ti setan lati se igbeyawo pelu ololufe re Kosi Obialor

Opolopo awon eyan lo jona ninu ijamba oko kan to sele ni ipinle Ondo

Ogbeni Omoyele Sowore lo se abewo si Alafin Oyo, Emir Kano ati awon ori ade miran fun igbaradi eto idibo Aare orilede ton bo ni odun 2019

Dele Momodu baba oni ikun nla, Davido ni ma fi ejo e sun - Lere Olayinka

Atejade oro Aare Buhari fun ayeye odun ijoba alagbada 2018

Igbakeji Aare orilede nigbakanri Atiku Abubakar ti fowosowpo pelu Gomina ipinle Ogun nigbakanri Otuba Gbenga Daniel lati gbaradi fun idibo Aare orilede ton bo ni odun 2019

Okolo (1-1) ni egbe agbaboolu Super Eagles ba egbe agbaboolu Congo gba ninu idije to waye laarin awon mejeji

Awon Fulani daran-daran lo se ikolu si ile iwe kan ni ipinle Taraba

O kere tan awon eyan merin ti so emi won nu ninu ijamba oko kan to sele ni opopona Benin si Auchi +18

Atejade Aare Muhammadu Buhari fun ayeye ojo awon omode

Iko egbe agbaboolu Real Madrid ti gbo omi ewuro si oju egbe agbaboolu Liverpool nigbati won na won ni omi ayo meta si ikan (3-1)