Posts

Ile igbimo asofin ti fowo si abadofin lati fi owo kun owo osu awon osise

Awon aworan oga agba egbe oloselu APC Asiwaju Bola Tinubu nibi abewo to lo se si Aare Buhari ni ilu Abuja

Opolopo awon eyan lo tun ti farapa nigba ti ile kan tun da-wo ni ilu Eko

Gbajugbaja oserebirin Seyi Ashekun ti bi omobirin lanti-lanti

O ma se o! Omo ile eko giga Usman Danfodiyo kan so emi re nu ninu ijamba oko

Awon olode kan ti gba oga olopa kan lowo awon ajinigbe ni ipinle Rivers

Gomina ipinle Ogun nigbakanri Otunba Gbenga Daniel ti kuro ninu egbe oloselu PDP bo si egbe oloselu APC

Jimi Agbaje oludije fun ipo Gomina ipinle Eko labe egbe oloselu PDP ki akegbe re labe egbe oloselu APC Babajide Sanwolu ku orire

#OTOGE! Abdulrahman Abdulrazaq lo wole gege bi Gomina ipinle Kwara labe egbe oloselu APC

Awon agbebon kan ti yin ibon pa omo egbe ile igbimo asofin Olatoye Temitope ‘Sugar’ ninu eto idibo to waye ni ipinle Oyo

Awon eyan mẹ́tàdínlọgọ́jọ lo ti so emi won nu ninu baalu to ja ni orilede Kenya

Awon agbofinro ti mu (Spirit) ogbontarigi onijibiti kan ni ipinle Katsina

Oserekunrin Tony Anyasador ti ku

Owo ajo EFCC ti ba arakunrin Anieka Udoh fun esun jibiti

Egbe agbaboolu Man-U ti fi agba han akegbe won PSG nigba ti won na won ni omi ayo meta si okan (3-1)

Atejade oro ti Aare Buhari so nipa eto idibo Gomina