Posts

Oga agba ati alukoro fun ile ise olopa Dolapo Badmus ti setan lati se igbeyawo ni ojo kini osu kejila (Dec 1).

Aare orilede nigba kan ri Goodluck Jonathan ati Senitor Ben Bruce ti ki gbajugbaja odomode olorin Wizkid ku ise latari ami eye MOBO ti won fi da lola.

Atejade awon to gba ami eye nibi ayeye MOBO Award 2017.

OYA, COME AND LEARN YORUBA PHRASES (FOR BEGINNERS). CLASS 1.

E gbami aradugbo, emi ati Adesua o fe ara wa ri o. Oserekunrin Kunle Remi lo so be.

Odomode kunrin olorin Mr2kay ti ra oko ayokele tuntun.

Awon agbebon (gun men) pa ojise Olorun kan ni ipinle Ondo.

Awon aworan Aare Buhari nibi ipade AU-EU Summit ni ilu Abidjan.

okòólénígba àti mẹwàá (230) ninu awon omo Nigeria ton se eru ni orilede Libya ti pada wale.

Awon adigunjale pa eyan meji ninu ikolu ti won se si ile ifowo pamo Diamond Bank towa ni ilu Okija, ipinle Anambra. +18

Gbajugaja osere ati alawada AY Makun ati Iyawo re n se ayeye ayajo odun kesan ti won se igbeyawo.

Owo awon agbofinro ti ba arakunrin kan to lu iyawo re pa ni ipinle Eko.

Aare Muhammadu Buhari ti pase fun awon Gomina ipinle lati san gbogbo owo osu awon osise ti won je ki odun Keresi to wole de.

Aare Buhari ki alaga egbe oloselu APC John Odigie-Oyegun ku araferakun lori bi Atiku Abubakar se fi egbe oloselu na sile.

Asita ibon (stray bullet) pa arakunrin kan ni ipinle Anambra.

Awako kan wako pa osise ajo FRSC kan ni ipinle Ondo.

Aare Buhari ti setan lati rin irin ajo lo si orilede Cote d’Ivoire ni ola.

Omo oba Harry ti se tan lati gbe orebirin re Meghan Markle ni iyawo.

Atiku Abubakar ti bere ipolongo fun eto idije fun ipo Aare orilede fun odun 2019.

Abala keji ayeye igbeyawo laarin Banky W ati Adesuwa ni orilede South Africa.