Posts

Oma se o, omo ile iwe giga Uniben kan pa iya re nitori owo ounje.

Ayeye ojo ibi Tiwaloluwa, omo gbajugbaja alawada Seyi Law.

An wa omokunrin omodun meta kan!.

Gomina ipinle Osun fi idunu re han nigba to pade ogbontarigi agbaboolu alafesegba Ogbeni Nwakwo Kanu.

Ijoba apapo ti yan ojo keji osu kewa (Oct 2nd) gege bi ojo isimi lati fi se ayeye odun ketadinlogota ti orilede Nigeria.

Oludasile ati alakoso ile ise Playboy Ogbeni Hugh Hefner ti ku.

Meet the Oyinbo Who Spoke Yoruba To The Ooni - Oloye Karin Barber.

Rogbodiyan ti be sile ni ilu Kogi laarin awon Akeko ati awon awako oko ajagbe Dangote to pa awon akeko marun kan ni opopona Lokoja si Abuja.. +18

Awon agbofinro ti mu awon okunrin mesan fun esun adigunjale ati ifipa-banilo ni ipinle Kano.

Awon agbofinro mu arakunrin kan ni ipinle Ekiti fun esun ifipa-banilo (rape).

Oloriburuku ni enikeni ti ko ba toju iya re. Odomode kunrin olorin Duncan Mighty lo so be.

Ijoba ipinle Eko ti yan Adajo Opeyemi Oke gege bi Adajo agba (chief judge) fun ipinle na.

Gomina ipine Eko, Akinwumi Ambode ti ra ero amunawa (generator) fun awon olopa lati ran ise won lowo.

Agbejoro Festus Keyamo se atejade kan lori ija to waye larin awon ibeji olorin Psquare.

Aburo Gomina ipinle Plateu, Solomon Dalung ti ku leyin aisan ranpe.

Ijakadi be si le laarin awon gbajugbaja ibeji olorin Psquare.

Arakunrin kan fo sanle lojiji o si ku ninu oja kan ni ipinle Adamawa.

Jude Okoye ati iyawo re ti bi omobirin lanti-lanti.

Aare Buhari ti pada de Abuja lati ipade UN General Assembly ni ilu New York.