Posts

Alabuku ati oni yeye lasan-lasan ni Obasanjo - Tinubu lo so be

Ko si iyato laarin Buhari ati Abacha - Olusegun Obasanjo lo so be

Aare Buhari ati akegbe re Atiku, ko orin won kere si numba wa nibi eto iforojomitoro-oro awon oludije fun ipo Aare orilede Nigeria #2019Debate

Iko egbe agbaboolu Arsenal fi agba han iko egbe agbaboolu Chelsea nigba ti won na won ni omi ayo meji si odo (2-0)

Ile ejo ti fun Senito Dino Melaye ni anfani lati lo mojuto eto ilera re

Babajide Sanwo-Olu, ogbontarigi oni diri

Ori ko Omo Oba Philip yo ninu ewu ijamba oko

Oludije fun ipo Aare Atiku Abubakar ati Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki lo se abewo ranpe si orilede America

Asoju orilede Nigeria si orilede Cote D'Ivoire ogbeni Ibrahim Isah ti ku

Ajo EFCC ti gbe ogbeni Doyin Okupelo si ile ejo fun esun jibiti to-to ẹ̀ẹ́dẹ̀gbẹ̀rin milionu naira

Owo awon agbofinro ti ba arakunrin to pa Iyawo ati awon omo re ni ipinle Edo

Oko ajagbe ya pa arabirin kan ati omo re ninu oja Oshodi +18

Ile ejo ti sun igbejo adajo agba Walter Onnoghen si ojo kejilelogun osu yi

Awon ọgọ́fà adajo lo ti gbaradi lati soju adajo agba Walter Samuel Nkanu Onnoghen ni ile ejo

"kaka k'eku ma je sese,yio ha fi se awada ni" Femi Fani Kayode lo so be

Aworan ati atejade oruko awon to gba ami eye nibi ayeye Soundcity MVP Awards fun odun 2019