Posts

Egbe agbaboolu Arsenal ti fi agba han egbe agbaboolu Southampton pelu omi ayo meji si odo (2-0)

Adesola Omidina, akobi gbajugbaja osere Baba Suwe ki awon ololufe baba re fun itoju ati ife

Awon agbebon kan ti ji Buba Galadima gbe ni ilu Abuja

Aworan Aare Muhamadu Buhari ninu oko re to wa ni ilu Daura

Omi ayo meta si odo (3-0) ni egbe agbaboolu Arsenal na egbe agbaboolu Bate

Ikede pataki lati enu Aare Buhari ni dede ago meje aro oni. E teti le ko!

Orilede China ti pinu lati fi owo sowopo pelu Nigeria lori eto isejoba

Alaga egbe oloselu PDP ni ipinle Yobe ti kuro ninu egbe na bo si egbe oloselu APC

Gbajugbaja oserekunrin Jussie Smollett ti wa ni atimole awon olopa

Keere O! Ajo INEC ti sun eto idibo siwaju

Owo awon agbofinro ti ba awon meji kan ti won gbiyanju lati ri ado oloro mo'le ni ipinle Ebonyi

Awon eyan merindiladorin lo ti so emi won nu ni ilu Kaduna latari atotonu eto idibo

Bisi, aburo gbajugbaja oserebirin Joke Silva ti ku latari aisan jejere

Ile ejo ti fi Babachir Lawal si atimole awon osise ajo EFCC

Egbe agbaboolu PSG ti fi agba han egbe agbaboolu Man-Utd nigba ti won na won ni omi ayo meji si odo (2-0)

Awon agbebon kan ti pa akapo egbe NURTW ogbeni Alowonle Asekun

Atejade oruko ati aworan awon to gba ami eye nibi ayeye Grammys 2019