Posts

Ogbeni Anthony Joshua lo gbe igba oroke nigba to fi ajeku iya je akegbe re Joseph Parker ninu idije ese-kikan to waye laarin awon mejeji.

#BBNAIJA. Odomodebirin BAMBAM ti ja kuro ninu idije BigbrotherNaija. (ogbeni Teddy-A, e ku araferakun)

Ile ejo ti da ejo iku fun Oloye kan ni ipinle Delta.

Owo awon agbofinro ti ba marun ninu awon odaran mefa to sa lo ni atimole awon olopa ni ipile Kogi.

Awon eyan meta lo ti ku ninu ikolu ti awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam se ni ilu Maiduguri.

Awon aworan nibi ojo ibi Asiwaju Bola Hammed Tinubu.

Awon odaran pa awon omologun mokanla kan ni ilu Kaduna.

Awon omoegbe okunkun kan se iku pa akeko ile eko giga Ambrose Alli.

Opuro, adojutini ati alai-lojuti ni igbakeji Aare Yemi Osinbajo. Femi Fani Kayode lo so be.

Aare Buhari ati oserebirin Naomi Campbell pade loni ni ipinle Eko.

Awon agbofinro mu odaran kan pelu agbari eyan meta ni ilu Ilorin.

Aworan ayeye ojo ibi Col. Mohammed Lawal Abubakar.

Oga agba pata-pata awon olopa Ibrahim Idris, ti da oga olopa ipinle Kogi, Ali Janga duro.

Owo ton da eru ba osi ni won fun mi ni ibi ayeye igbeyawo Fatima Dangote. Ogbeni Swanky Jerry lo so be.

Awon olopa ton soju ipinle Kogi ti pinu lati fi Senator Dino Melaye si atimole.

Ile iwe giga Unifasiti ti Ibadan ti setan lati le awon akeko kan latari wipe won o dangajia to lenu eko won.

Iko egbe agbaboolu orilede Serbia na egbe agbaboolu Super eagles ni omi ayo meji si odo (2-0)

Aare Buhari ti setan lati lo se abewo si ipinle Eko.

Oserebirin Adesua Etomi ki oko re Banky W ku ayeye ojo ibi.