Posts

Opolopo awon omo egbe Shitte lo so emi won nu ninu ikolu to waye pelu awon omo ologun Nigeria

Aworan nibi eto isinku Efemena Okedi, iyawo ologbe Ras Kimono

Arabirin Zewde Sahle-Work ni Aare orilede Ethiopia tuntun

Apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla

Gbajugbaja olorin takasufe orilede South Africa HHP ti ku

O MA SE O! Oluko agba kan ni ipinle Benue gba emi ara re

Awon eyan mesan lo so emi won nu ninu ijamba oko kan to waye ni opopona Eko si Ibadan

Gbajugbaja odomode olorin WizKid ati akegbe re Tiwa Savage ti se obe alata suwe-suwe

Ola ni eto isinku Adajo agba Idris Lebo Kutigi

Awon agbofinro ti bere iwadi lori iku omidan Seun Ajila

Olori Alaafin Oyo, (IKU BABA-YEYE) tun ti bi ibije lanti-lanti

Ilu Jerusalemu ni adari egbe ajijagbara fun orilede Biafra Nnamdi Kanu wa

Aworan nibi ayeye igbeyawo laarin Ooni Ife Oba Adeyeye Ogunwusi ati ajihinrere Naomi Oluwaseyi

Aworan nibi ayeye ibura fun ni gbangba Gomina ipinle Ekiti tuntun Kayode Fayemi

Oni ni ayeye ojo ibi odun kẹ́rìndínlọ́gọ́rin oserebirin agba Iya Rainbow

Yoruba History; (Ibadan and Witty Sayings)

Gbajugbaja olorin takasufe Kanye West ati iyawo re Kim Kardashian lo se abewo si Aare orilede Uganda Yoweri Museveni

Ijoba ipinle Kano ti bere iwadi lori esun jibiti ti won fi kan Gomina Abdullahi Umar Ganduje

Ibanuje nla ni iku arabirin Hauwa Leman je fun orilede Nigeria- Ijoba apapo lo so be

Awon aworan nibi ayeye ifeyinti Ayodele Fayose gege bi Gomina ipinle Ekiti