Posts

Baba gbajugbaja odomode olorin African China ti ku.

O ma se o, odomodebirin kan ku leyin ojo mokanla to se igbeyawo.

Oni ni ojo ibi gbajugbaja oserebirin Jocelyn Dumas.

Awon olopa mu awon ogbontarigi ajinigbe kan ni ipinle Kogi.

Akojopo awon OBO ati INAKI ni awon to wani ijoba Aare Buhari.. Femi Fani Kayode lo so be.

Ijoba apapo ti yan igbakeji Aare Yemi Osinbajo gege bi agbenuso laarin ijoba ati awon omo egbe ASUU.

Omo egbe agbaboolu Super Eagles Emmanuel Emenike ati ololufe re Iheoma ti bi omobirin.

Awon Gomina lo se ipade pelu olori awon ajijagbara fun orilede Biafra Nnamdi Kanu.

Aare Buhari gba awon omobirin agbaboolu alafowo gba 'D'TIGRESS' (female basketballer's) ni alejo ni Abuja.

Awon agbofinro ti ri odomode kunrin to sonu ni ilu Warri ni ipinle Eko.

Marun ninu awon omo Nigeria to rin irin ajo Hajj lo si orilede Saudi Arabia ni won ti so emi won nu.

Dele Momodu ki olori nigbakan ri arabirin Zainabu Obanor ku iroju ati ifarada.

Olori nigbakan ri arabirin Zainab Obanor ti jewo wipe ohun ti kuro ni afin Ooni Adeyeye Ogunwusi.

Ile ejo ti sun igbejo ogbontarigi ajinigbe Evans si iwaju.

Awon omo egbe ASUU ko lati lo se ipade pelu ijoba apapo.

Omobirin Gomina ipinle Cross River nigbakan ri Xerona Duke ati oko afesona re Derin Phillips ti gbogbo eyan mo si DJ Caise ti setan lati gbe ara won ni iyawo.

Owo awon agbofinro ti ba awon odaran meji kan ti won man ta eya ara eyan fun ogun owo ni ipinle Niger. +18

Awon olopa ti bere iwadi lori omo odun mewa ti won pa ninu oja Eke Ukwu ni ipinle Imo.

Ijoba apapo ti fun awon osise ni isimi ni ojo kini ati ojo kerin osu kesan lati fi se ayeye odun Ileya.

Ori ko egbon gomina ipinle Ekiti, Ayodele Fayose yo ninu ewo ijamba oko ni opopona Abuja si Ekiti.

Ogbeni Mark Zuckerberg ati iyawo re Priscilla Chan ti bi omobirin lanti-lanti.

Gbajugbaja oserekunrin Obi Madubogwu ti ku.

Ogbeni Tony Nwoye lo jawe olubori gege bi oludije fun ipo Gomina ni abe egbe oloselu APC ni Ipinle Anambra.

Omo egbe ile igbimo asofin nigbakan ri Olufemi Onimole ti ku.

Awon Fulani Daran-daran kan fi ada sa arakunrin agbe kan ni ipinle Enugu.

Oserebirin Mercy Johnson ati oko re Omoba Odi Okojie fi ife han si ara won lati se ayeye odun kefa igbeyawo won.