Posts

Aworan nibi abewo ti Aare Buhari se si awon molebi ologbe Shehu Shagari

Gbajugbaja olorin Dr Sid ati iyawo re ti bi omobirin tuntun jojolo

Awon agbebon yin ibon pa oloselu kan ni ipinle Ekiti

Aare orilede Nigeria nigbakanri Alhaji Shehu Shagari ti ku

Oga olopa yin ibon pa ogagun kan ni ilu Calabar

Awon aworan nibi ayeye igbeyawo to waye laarin Prince Aminu Sanusi ati ololufe re Zainabu

Awon agbofinro ti mu awon eyan merin ti won fura si wipe won lowo ninu iku ogagun Alex Badeh

Odomodebirin kan so emi re nu nigba to jana mo oko lenu ni ipinle Eko

Aku odun Keresimesi o, Odun a yabo fun gbogbo wa

Gbajugbaja olorin Timaya ra oko ayokele G-Wagon ati Maybach lati se ayeye odun keresi

Ojogbon Sophie Oluwole (Mamalawo) ti ku

Opolopo awon eyan farapa ninu ijamba oko kan to waye lori afara Third Mainland bridge ni ipinle Eko

Oserebirin Funke Akindele ti bi ibeji lanti-lanti (Ayo abara tintin)

Ijakadi waye laarin Yemi alade ati akegbe re Tiwa Savage nitori ikebe

Opolopo awon dukia lo sofo ninu ijamba ina to sele ninu oja Keffi ni ipinle Nassarawa

Chike, omo agba oloselu Edwin Clark ti ku

Afinju sorosoro Toolz ati oko re Tunde Demuren ti bi omokunrin lanti-lanti

Amaka ti doju ti gbajugbaja olorin Peruzzi

Oma se o! Odomodekunrin agunbaniro kan so emi re nu ninu ijamba oko ni ipinle Kano

Aworan oludije fun ipo Aare Atiku Abubakar nibi to tin fi owo siwe idibo ni alafia

Opolopo awon eyan lo ti so emi won nu ninu ikolu awon agbebon to waye ni ipinle Zamfara

Ile ejo ti sun igbejo adajo agba Paul Usoro siwaju

Oni ni ayeye ojo ibi odun karundinlogbon gbajugbaja olorin Reekado Banks

Emi gan-gan le'mi won o ni fi elo mi se mi - Aare Buhari lo so be

Luca Modric lo gba ami eye agbaboolu to dangajia julo ni agbaye nibi ayeye Ballon d'Or awards

Owo awon agbofinro ti ba ilu mo'ka olorin Small Doctor

Aare orilede Nigeria nigbakanri Goodluck Jonathan ati iyawo re lo se abewo si ile alaja meje to wo ni ipinle Rivers